Kọrinti Kinni 9:27 BM

27 Ṣugbọn mò ń fi ìyà jẹ ara mi, mò ń kó ara mi ní ìjánu. Ìdí ni pé nígbà tí mo bá ti waasu fún àwọn ẹlòmíràn tán, kí èmi alára má baà di ẹni tí kò ní yege ninu iré-ìje náà.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 9

Wo Kọrinti Kinni 9:27 ni o tọ