Kọrinti Kinni 9:5 BM

5 Ṣé a kò ní ẹ̀tọ́ láti máa mú aya lọ́wọ́ ninu ìrìn àjò wa gẹ́gẹ́ bí àwọn aposteli yòókù ati àwọn arakunrin Oluwa ati Peteru?

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 9

Wo Kọrinti Kinni 9:5 ni o tọ