Luku 1:80 BM

80 Ọmọ náà ń dàgbà, ó sì ń lágbára sí i lára ati lẹ́mìí. Ilẹ̀ aṣálẹ̀ ni ó ń gbé títí di àkókò tí ó fara han àwọn eniyan Israẹli.

Ka pipe ipin Luku 1

Wo Luku 1:80 ni o tọ