Luku 10:6 BM

6 Bí ọmọ alaafia bá wà níbẹ̀, alaafia yín yóo máa wà níbẹ̀. Bí kò bá sí, alaafia yín yóo pada sọ́dọ̀ yín.

Ka pipe ipin Luku 10

Wo Luku 10:6 ni o tọ