Luku 12:39 BM

39 Kí ẹ mọ èyí pé bí ó bá jẹ́ pé baálé ilé mọ àkókò tí olè yóo dé, kò ní fi ilé rẹ̀ sílẹ̀ kí olè kó o.

Ka pipe ipin Luku 12

Wo Luku 12:39 ni o tọ