Luku 13:29 BM

29 Àwọn eniyan yóo wá láti ìlà oòrùn ati láti ìwọ̀ oòrùn, láti àríwá ati láti gúsù, wọn yóo jókòó níbi àsè ní ìjọba Ọlọrun.

Ka pipe ipin Luku 13

Wo Luku 13:29 ni o tọ