Luku 15:24 BM

24 Nítorí ọmọ mi yìí ti kú, ṣugbọn ó tún wà láàyè; ó ti sọnù, ṣugbọn a ti rí i.’ Ni wọ́n bá bẹ̀rẹ̀ sí ṣe àríyá.

Ka pipe ipin Luku 15

Wo Luku 15:24 ni o tọ