Luku 17:15 BM

15 Nígbà tí ọ̀kan ninu wọn rí i pé ara òun ti dá, ó pada, ó ń fi ìyìn fún Ọlọrun pẹlu ohùn gíga.

Ka pipe ipin Luku 17

Wo Luku 17:15 ni o tọ