Luku 2:16 BM

16 Wọ́n bá yára lọ. Wọ́n wá Maria kàn ati Josẹfu ati ọmọ-ọwọ́ náà tí a tẹ́ sí ibùjẹ ẹran.

Ka pipe ipin Luku 2

Wo Luku 2:16 ni o tọ