Luku 20:2 BM

2 Wọ́n bi í pé, “Sọ fún wa irú àṣẹ tí o fi ń ṣe àwọn nǹkan wọnyi; ta ni ó sì fún ọ ní àṣẹ yìí?”

Ka pipe ipin Luku 20

Wo Luku 20:2 ni o tọ