Luku 20:47 BM

47 Wọn a máa jẹ ilé àwọn opó run. Wọ́n a máa gba adura gígùn láti ṣe àṣehàn. Wọn yóo gba ìdájọ́ líle.”

Ka pipe ipin Luku 20

Wo Luku 20:47 ni o tọ