Luku 22:53 BM

53 Ṣebí ojoojumọ ni mo wà pẹlu yín ninu Tẹmpili. Ẹ kò ṣe fọwọ́ kàn mí? Ṣugbọn àkókò yín ati ti aláṣẹ òkùnkùn nìyí.”

Ka pipe ipin Luku 22

Wo Luku 22:53 ni o tọ