Luku 23:36 BM

36 Àwọn ọmọ-ogun náà ń fi ṣe yẹ̀yẹ́. Wọ́n fún un ní ọtí pé kí ó mu ún.

Ka pipe ipin Luku 23

Wo Luku 23:36 ni o tọ