Luku 23:55 BM

55 Àwọn obinrin tí wọn bá Jesu wá láti Galili tẹ̀lé Josẹfu yìí, wọ́n ṣe akiyesi ibojì náà, ati bí a ti ṣe tẹ́ òkú Jesu sinu rẹ̀.

Ka pipe ipin Luku 23

Wo Luku 23:55 ni o tọ