Luku 24:28 BM

28 Nígbà tí wọ́n súnmọ́ abúlé tí wọn ń lọ, Jesu ṣe bí ẹni pé ó fẹ́ máa bá ìrìn àjò rẹ̀ lọ.

Ka pipe ipin Luku 24

Wo Luku 24:28 ni o tọ