Luku 5:34 BM

34 Jesu dá wọn lóhùn pé, “àwọn ọ̀rẹ́ ọkọ iyawo kò lè máa gbààwẹ̀ níwọ̀n ìgbà tí ọkọ iyawo bá wà pẹlu wọn.

Ka pipe ipin Luku 5

Wo Luku 5:34 ni o tọ