Luku 5:5 BM

5 Simoni dáhùn pé, “Alàgbà, gbogbo òru ni a fi ṣiṣẹ́ láì rí ohunkohun pa, ṣugbọn nítorí ọ̀rọ̀ rẹ, n óo da àwọ̀n sí omi.”

Ka pipe ipin Luku 5

Wo Luku 5:5 ni o tọ