Luku 6:25 BM

25 Ẹ̀yin tí ẹ yó nisinsinyii, ẹ gbé,nítorí ebi ń bọ̀ wá pa yín.Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń yọ̀ nisinsinyii, ẹ gbé,nítorí ọ̀fọ̀ óo ṣẹ̀ yín, ẹ óo sì sunkún.

Ka pipe ipin Luku 6

Wo Luku 6:25 ni o tọ