Luku 6:3 BM

3 Jesu dá wọn lóhùn pé, “Ṣé ẹ kò ì tíì ka ohun tí Dafidi ṣe nígbà tí ebi ń pa òun ati àwọn tí ó wà pẹlu rẹ̀?

Ka pipe ipin Luku 6

Wo Luku 6:3 ni o tọ