Luku 9:32 BM

32 Ṣugbọn oorun ti ń kun Peteru ati àwọn tí ó wà pẹlu rẹ̀. Nígbà tí wọ́n tají, wọ́n rí ògo rẹ̀ ati àwọn ọkunrin meji tí wọ́n dúró tì í.

Ka pipe ipin Luku 9

Wo Luku 9:32 ni o tọ