Luku 9:49 BM

49 Johanu sọ fún un pé, “Ọ̀gá, a rí ẹnìkan tí ń fi orúkọ rẹ lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde. A fẹ́ dá a lẹ́kun nítorí kì í ṣe ara wa.”

Ka pipe ipin Luku 9

Wo Luku 9:49 ni o tọ