Luku 9:54 BM

54 Nígbà tí àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀, Jakọbu ati Johanu, rí i, wọ́n ní, “Oluwa, ṣé o fẹ́ kí á pe iná láti ọ̀run kí ó jó wọn pa?”

Ka pipe ipin Luku 9

Wo Luku 9:54 ni o tọ