Tẹsalonika Kinni 1:10 BM

10 ati bí ẹ ti ń retí Jesu, Ọmọ rẹ̀, láti ọ̀run wá, ẹni tí a jí dìde ninu òkú, tí ó yọ wá kúrò ninu ibinu tí ń bọ̀.

Ka pipe ipin Tẹsalonika Kinni 1

Wo Tẹsalonika Kinni 1:10 ni o tọ