Tẹsalonika Kinni 1:6 BM

6 Ẹ̀yin náà wá ń fara wé wa, ẹ sì ń fara wé Oluwa. Láàrin ọpọlọpọ inúnibíni ẹ gba ọ̀rọ̀ ìyìn rere tayọ̀tayọ̀ láti ọ̀dọ̀ Ẹ̀mí Mímọ́.

Ka pipe ipin Tẹsalonika Kinni 1

Wo Tẹsalonika Kinni 1:6 ni o tọ