Tẹsalonika Kinni 1:8 BM

8 Nítorí ẹ̀yin ni ẹ tan ìyìn rere ọ̀rọ̀ Oluwa káàkiri, kì í ṣe ní Masedonia ati Akaya nìkan, ṣugbọn níbi gbogbo ni ìròyìn igbagbọ yín sí Ọlọrun ti tàn dé. Kò ṣẹ̀ṣẹ̀ tún ní pé à ń sọ ohunkohun mọ́.

Ka pipe ipin Tẹsalonika Kinni 1

Wo Tẹsalonika Kinni 1:8 ni o tọ