Tẹsalonika Kinni 3:12 BM

12 Kí Oluwa mú kí ìfẹ́ yín sí ara yín ati sí gbogbo eniyan kí ó pọ̀ sí i, kí ó sì túbọ̀ jinlẹ̀, gẹ́gẹ́ bí tiwa ti rí si yín.

Ka pipe ipin Tẹsalonika Kinni 3

Wo Tẹsalonika Kinni 3:12 ni o tọ