Tẹsalonika Kinni 4:13 BM

13 Ẹ̀yin ará, àwa kò fẹ́ kí ẹ má ní òye nípa àwọn tí wọ́n ti sùn, kí ẹ má baà banújẹ́ bí àwọn tí kò nírètí.

Ka pipe ipin Tẹsalonika Kinni 4

Wo Tẹsalonika Kinni 4:13 ni o tọ