Tẹsalonika Kinni 4:15 BM

15 Nítorí à ń sọ ọ̀rọ̀ yìí fun yín gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ Oluwa, pé àwa tí a bá wà láàyè, tí a bá kù lẹ́yìn nígbà tí Oluwa bá farahàn, kò ní ṣiwaju àwọn tí wọ́n ti kú.

Ka pipe ipin Tẹsalonika Kinni 4

Wo Tẹsalonika Kinni 4:15 ni o tọ