Tẹsalonika Kinni 5:13 BM

13 Ẹ máa fi ìfẹ́ yẹ́ wọn sí gidigidi nítorí iṣẹ́ wọn. Ẹ máa wà ní alaafia láàrin ara yín.

Ka pipe ipin Tẹsalonika Kinni 5

Wo Tẹsalonika Kinni 5:13 ni o tọ