Tẹsalonika Kinni 5:18 BM

18 Ẹ máa dúpẹ́ ninu ohun gbogbo nítorí èyí ni ìfẹ́ Ọlọrun nípa Kristi Jesu fun yín.

Ka pipe ipin Tẹsalonika Kinni 5

Wo Tẹsalonika Kinni 5:18 ni o tọ