Tẹsalonika Kinni 5:5 BM

5 Nítorí ọmọ ìmọ́lẹ̀ ni gbogbo yín; ọmọ tí a bí ní àkókò tí ojú ti là sí òtítọ́, ẹ kì í ṣe àwọn tí a bí ní àkókò àìmọ̀kan; ẹ kì í ṣe ọmọ òkùnkùn.

Ka pipe ipin Tẹsalonika Kinni 5

Wo Tẹsalonika Kinni 5:5 ni o tọ