Dan 11:34 YCE

34 Njẹ nisisiyi, nigbati nwọn o ṣubu, a o fi iranlọwọ diẹ ràn wọn lọwọ: ṣugbọn ọ̀pọlọpọ ni yio fi ẹ̀tan fi ara mọ́ wọn.

Ka pipe ipin Dan 11

Wo Dan 11:34 ni o tọ