Dan 6:5 YCE

5 Nigbana ni awọn ọkunrin wọnyi wipe, Awa kì yio le ri ẹ̀sùn kan si Danieli bikoṣepe a ba ri i si i nipasẹ ofin Ọlọrun rẹ̀.

Ka pipe ipin Dan 6

Wo Dan 6:5 ni o tọ