Dan 9:10 YCE

10 Bẹ̃li awa kò si gbà ohùn Oluwa Ọlọrun wa gbọ́, lati ma rìn nipa ofin ti o gbé kalẹ niwaju wa lati ọwọ awọn iranṣẹ rẹ̀, awọn woli wá.

Ka pipe ipin Dan 9

Wo Dan 9:10 ni o tọ