Dan 9:3 YCE

3 Emi si kọju mi si Oluwa Ọlọrun, lati ma ṣafẹri nipa adura ati ẹ̀bẹ, pẹlu àwẹ, ninu aṣọ-ọ̀fọ, ati ẽru.

Ka pipe ipin Dan 9

Wo Dan 9:3 ni o tọ