Dan 9:8 YCE

8 Oluwa, tiwa ni itiju, ti awọn ọba wa, ati awọn olori wa, ati ti awọn baba wa, nitori ti awa ti ṣọ̀tẹ si ọ.

Ka pipe ipin Dan 9

Wo Dan 9:8 ni o tọ