Mik 1:16 YCE

16 Sọ ara rẹ di apari, si rẹ́ irun rẹ nitori awọn ọmọ rẹ ẹlẹgẹ́; sọ apári rẹ di gbòro bi idì; nitori a dì wọn ni igbèkun lọ kuro lọdọ rẹ.

Ka pipe ipin Mik 1

Wo Mik 1:16 ni o tọ