Mik 2:1 YCE

1 EGBE ni fun awọn ti ngbìmọ aiṣedede, ti nṣiṣẹ ibi lori akete wọn! nigbati ojumọ́ mọ́ nwọn nṣe e, nitoripe o wà ni agbara ọwọ́ wọn.

Ka pipe ipin Mik 2

Wo Mik 2:1 ni o tọ