Mik 7:16 YCE

16 Awọn orilẹ-ède yio ri, oju o si tì wọn ninu gbogbo agbara wọn: nwọn o fi ọwọ́ le ẹnu, eti wọn o si di.

Ka pipe ipin Mik 7

Wo Mik 7:16 ni o tọ