Mik 7:17 YCE

17 Nwọn o lá erùpẹ bi ejò, nwọn o si jade kuro ninu ihò wọn bi ekòlo ilẹ: nwọn o bẹ̀ru Oluwa Ọlọrun wa, nwọn o si bẹ̀ru nitori rẹ.

Ka pipe ipin Mik 7

Wo Mik 7:17 ni o tọ