Nah 1:5 YCE

5 Awọn oke-nla mì nitori rẹ̀, ati awọn oke kékèké di yiyọ́, ilẹ aiye si joná niwaju rẹ̀, ani aiye ati gbogbo awọn ti ngbe inu rẹ̀.

Ka pipe ipin Nah 1

Wo Nah 1:5 ni o tọ