Nah 3:9 YCE

9 Etiopia ati Egipti li agbara rẹ̀, kò si li opin; Puti ati Lubimu li awọn olùranlọwọ rẹ.

Ka pipe ipin Nah 3

Wo Nah 3:9 ni o tọ