18 Nitori bi ijogun na ba ṣe ti ofin, kì iṣe ti ileri mọ́: ṣugbọn Ọlọrun ti fi i fun Abrahamu nipa ileri.
Ka pipe ipin Gal 3
Wo Gal 3:18 ni o tọ