1. Kor 1:21 YCE

21 Nitoripe ninu ọgbọ́n Ọlọrun niwọnbi aiye kò ti mọ̀ nitori ọgbọ́n, o wù Ọlọrun nipa wère iwasu lati gbà awọn ti o gbagbọ́ là.

Ka pipe ipin 1. Kor 1

Wo 1. Kor 1:21 ni o tọ