21 Ẹnyin kò le mu ago Oluwa ati ago awọn ẹmi èṣu: ẹnyin kò le ṣe ajọpin ni tabili Oluwa, ati ni tabili awọn ẹmi èṣu.
Ka pipe ipin 1. Kor 10
Wo 1. Kor 10:21 ni o tọ