1. Kor 10:27 YCE

27 Bi ọkan ninu awọn ti kò gbagbọ́ ba pè nyin sibi àse, bi ẹnyin ba si fẹ ilọ; ohunkohun ti a ba gbé kalẹ niwaju nyin ni ki ẹ jẹ, laibere ohun kan nitori ẹri-ọkàn.

Ka pipe ipin 1. Kor 10

Wo 1. Kor 10:27 ni o tọ