1. Kor 10:9 YCE

9 Bẹ̃ni ki awa ki o máṣe dán Oluwa wò, gẹgẹ bi awọn miran ninu wọn ti dán a wò, ti a si fi ejò run wọn.

Ka pipe ipin 1. Kor 10

Wo 1. Kor 10:9 ni o tọ