3 Ṣugbọn mo fẹ ki ẹnyin ki o mọ̀ pe, Kristi li ori olukuluku ọkunrin; ori obinrin si li ọkọ rẹ̀; ati ori Kristi si li Ọlọrun.
Ka pipe ipin 1. Kor 11
Wo 1. Kor 11:3 ni o tọ