1. Kor 11:34 YCE

34 Bi ebi ba npa ẹnikẹni, ki o jẹun ni ile; ki ẹnyin ki o má bã pejọ fun ẹbi. Iyokù li emi ó si tò lẹsẹsẹ nigbati mo ba de.

Ka pipe ipin 1. Kor 11

Wo 1. Kor 11:34 ni o tọ