1. Kor 12:23 YCE

23 Ati awọn ẹ̀ya ara wọnni ti awa rò pe nwọn ṣe ailọlá jù, lori wọnyi li awa si nfi ọlá si jù; bẹni ibi aiyẹ wa si ni ẹyẹ lọpọlọpọ jù.

Ka pipe ipin 1. Kor 12

Wo 1. Kor 12:23 ni o tọ